peoplepill id: dupe-jayesinmi
DJ
Nigeria
8 views today
14 views this week
Dupe Jayesinmi
Nigerian Actress

Dupe Jayesinmi

The basics

Quick Facts

Intro
Nigerian Actress
Places
Gender
Female
The details (from wikipedia)

Biography

Dúpẹ́ Jáyésinmi tí yóò pé ọmọ ọdún ménìlélọ́gọ́ta (62) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí Ìjẹ̀bú igbó ni ìpínlẹ̀ Ògùn, ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

Dúpẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní Seventh Day Adventist Primary School ní Ilé-Ìfẹ́ , ó tẹ̀ síwájú ní CAC Commercial High School tí wọ́n ń pè ní CAC High School ní ìlú Iléṣà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Bákan náà ó lọ sí Sight & Sound International School, Ìbàdàn, lẹ́yìn èyí ó kàwé gboyè nínú iṣẹ́ Akọ̀wé Ìbàdàn Polytechnic. "No Rival" ni àkọ́lé sinimá àgbéléwò tó mú kí ìràwọ̀ Dúpẹ́ Jáyésinmi tán síta. Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá. . Ọmọ ìjọ Mímọ́ ni Dúpẹ́.

Àwọn Ìtọ́kasí

The contents of this page are sourced from Wikipedia article. The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Dupe Jayesinmi is in following lists
comments so far.
Comments
From our partners
Sponsored
Credits
References and sources
Dupe Jayesinmi
arrow-left arrow-right instagram whatsapp myspace quora soundcloud spotify tumblr vk website youtube pandora tunein iheart itunes