peoplepill id: dele-odule-1
DO
2 views today
9 views this week
The basics

Quick Facts

The details (from wikipedia)

Biography

A bí Délé Òdúlé tí a bí lọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù kọkànlá ọdún 1961 jẹ́ àgbà òṣèré tíátà àti olótùú-àgbà. Ní ọdún 2014, wọ́n yaǹ-án láti gba àmìn-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré Yorùbá ni (Best of Nollywood Awards) fún ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò "Kori Koto". Òun ààrẹ àwọn òṣèré tíátà àti sinimí àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ìgbéayé Délé Òdúlé Ni Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Àti Bí Ó Ti Kẹ́kọ̀ọ́

A bí Délé Òdúlé ní ìlú Òrù-Ìjèbù, Ní Ìjọba Ìbílè Ijebu North ti ìpínlẹ Ogun ní ọdún 1961.  Ibè ni ó ti ka ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti gíga. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Olùkọ̀ onípele kejì (Teachers' Grade II Certificate) ní Oru kí ó tó tẹ̀síwájụ́ ẹ̀kọ́ ní University of Ibadan, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ níbi tí ó ti ń kọ́ nípa ìmọ̀ tíátà (Theatre Arts.)

Àdàkọ:Inc-filmInc-film

Awọn atokọ ti eré re

  • Ti Oluwa Ni Ile (1993)
  • Lakunle Alagbe (1997)
  • Oduduwa (2000)
  • Afonja (2002)
  • Olorire (2003)
  • Ògédé Didùn (2003)
  • Ogbologbo (2003)
  • Suku Suku Bam Bam (2004)
  • Omo Olè (2004)
  • Iwe Akosile (2005)
  • Idajo Mi Tide (2005)
  • Eru Ife (2005)
  • Ó kojá Ofin (2007)
  • Aye Ibironke (2007)
  • Bolode O'ku (2009)
  • Aworo (2012)
The contents of this page are sourced from Wikipedia article. The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Dele Odule is in following lists
comments so far.
Comments
From our partners
Sponsored
Credits
References and sources
Dele Odule
arrow-left arrow-right instagram whatsapp myspace quora soundcloud spotify tumblr vk website youtube pandora tunein iheart itunes