peoplepill id: afeez-eniola
AE
Nigeria
1 views today
2 views this week
The basics

Quick Facts

Intro
Nigerian actor
Places
Gender
Male
Place of birth
Lagos State, Nigeria
Family
The details (from wikipedia)

Biography

Afeez Ẹniọlá tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì jẹ́ òṣeré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ìgbà èwe rẹ̀

Wọ́n bí Afeez Ẹniọlá lọ́jọ́ kejìlélógún oṣù kejì (22nd February) ní ìlú ṣómólú ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó náà ló ti kàwé. Gbajúmọ̀ òṣèré tíátà ni, ó fẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Esther Kálèjayé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọmọ jọ yíbò. Afeez dara pọ̀ mọ́ àwọn eléré tíátà fún ìgbà pípẹ́ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ òṣèrébìnrin kan tí ó ń jẹ́ Bọ́sẹ̀ Olúbọ̀. Lẹ́yìn náà, Afeez tí kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó ti ju ọgọ́rùn-ún lọ

Àwọn Ìtọ́kasí

The contents of this page are sourced from Wikipedia article. The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Afeez Eniola is in following lists
comments so far.
Comments
From our partners
Sponsored
Credits
References and sources
Afeez Eniola
arrow-left arrow-right instagram whatsapp myspace quora soundcloud spotify tumblr vk website youtube pandora tunein iheart itunes