peoplepill id: oluwarotimi-odunayo-akeredolu-1
Nigeria politician
Oluwarotimi Odunayo Akeredolu
The basics
Quick Facts
Intro
Nigeria politician
Star sign
Age
68 years
The details (from wikipedia)
Biography
Àdàkọ:EngvarB
Olúwarótìmí Ọdúnayọ̀ Akérédolú, SAN, or Rótìmí Akérédolú, ní wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù keje ọdún 1956 (21st July 1956) jẹ́ òṣèlú, agbẹjọ́rọ̀ àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́wọ́lọ́wọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà , Ó jẹ́ amòfin-àgbà SAN tí ó ti joyè alága àwọn amọ̀fin Nigerian Bar Association lọ́dún 2008. Kí ó tó di Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, ó jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ amọ̀fin, Olujinmi & Akeredolu, a Law Firm he co-founded with Chief Akin Olujinmi, a former Attorney General and Minister for Justice in Nigeria. Ó gbapò ìṣèjọba ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́wọ́ Gómìnà-àná ti ìpínlẹ̀ náà, Olúṣẹ́gun Mimiko
Àwọn Ìtọ́kasí
The contents of this page are sourced from Wikipedia article.
The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Oluwarotimi Odunayo Akeredolu is in following lists
By work and/or country
By category
comments so far.
Comments
Credits
References and sources
Oluwarotimi Odunayo Akeredolu