peoplepill id: mide-f-m-abiodun-1
Nigerian actress
Mide F.M Abiodun
The basics
Quick Facts
Intro
Nigerian actress
Places
is
Work field
Gender
Female
Star sign
Age
45 years
Family
Spouse:
The details (from wikipedia)
Biography
Midé Fúnmi Martins (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1979) jẹ́ Òṣeré-bìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé Fúnmi Martins tó ṣaláìsí lọ́dún 2002. Midé Martins darapọ̀ mọ́ àwọn Òṣeré sinimá àgbéléwò ní kété tí ìyá rẹ di olóògbé. Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ sí Afeez Owó. Ọmọ méjì ni ó bí .
Àwọn Ìtọ́kasí
The contents of this page are sourced from Wikipedia article.
The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Mide F.M Abiodun is in following lists
comments so far.
Comments
Credits
References and sources
Mide F.M Abiodun