peoplepill id: aina-gold
Nigerian Actor
Aina Gold
The basics
Quick Facts
Intro
Nigerian Actor
Places
is
Work field
Gender
Male
Place of birth
Lagos, Lagos State, Nigeria
Star sign
Age
61 years
Education
Yaba College of Technology
Lagos, Lagos State, Nigeria
The details (from wikipedia)
Biography
Aina Gold (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹta ọdún 1963) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò. Ó tún jẹ́ gbajúgbajà onímọ̀ káràkátà ilé àti ilẹ̀.
Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀
Àìná Gold kàwé gboyè ni ilé ìwé gíga ti Yaba Tech, ní ìlú Èkó. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà gẹ́gẹ́ bí olúkọ́ṣẹ́ lábẹ́ Òṣùmàrè Theatre Group àti àgbà òṣèrébìnrin, Ìdòwú Phillips tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ìyá Rainbow. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa pàtàkì, lára wọn ní Alápátirá, Àgékù Àbẹ́là, Ẹ̀rùkẹ́rù, Ìlù Gángan, Akoto Ọlọ́kadà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Yàtọ̀ sí iṣẹ́ tíátà, Àìná Gold tún ní olùdásílẹ̀ ilé ìṣe Àìná Gold Estate ní ìlú Abẹ́òkúta olú ìlú ìpínlẹ̀ Ògùn, àti Multi-Choice Estate ní ìpínlẹ̀ Èkó.
Àwọn Ìtọ́kasí
The contents of this page are sourced from Wikipedia article.
The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.
Lists
Aina Gold is in following lists
By field of work
By work and/or country
comments so far.
Comments
Credits
References and sources
Aina Gold