Yemi Ayebo

Nigerian Actor
The basics

Quick Facts

IntroNigerian Actor
A.K.A.Yemi my lover
A.K.A.Yemi my lover
PlacesNigeria
isActor Film producer
Work fieldFilm, TV, Stage & Radio
Gender
Male
The details

Biography

Yẹmí Ayébọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Yẹmí My Lover jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé òun sinimá, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Òndó.

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà ní ọdún 1983, lásìkò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ oníwé Mẹ́wá, tí ó sì ko pa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré sinimá àgbéléwò Yorùbá. Eré sinimá tí ó gbe jáde ní àsìkò ọdún 1990s ni Yẹmí My Lover tí ó sì padà di orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ títí dòní.

Àwọn eré sinimá rẹ̀

Lára àwọn eré tí ó ti gbe jáde ni

  1. Yẹmí My Lover
  2. Yẹmí in the Moon
  3. Má danwò àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àwọn ìtọ́kasí

The contents of this page are sourced from Wikipedia article on 21 Aug 2024. The contents are available under the CC BY-SA 4.0 license.