Tola Oladokun
Nigerian Actress
Intro | Nigerian Actress | |
Places | Nigeria | |
is | Actor Radio personality Film producer | |
Work field | Film, TV, Stage & Radio | |
Gender |
| |
Birth | Oyo State, Nigeria |
Ọwọ́mitọ́lá Oládòkun tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ìka lọmọ Ejò jẹ́ gbajú gbajà òṣèré orí-ìtàgé Yorùbá, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bi ní ìlú Ìgàngàn tí ó jẹ ọ̀ was ọ̀kan lára àwọn ìlú Ìbàràpá méjèèjé ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti Girama ní Ilé-Ẹ̀kọ́ Methodist Primary School tí ó wà ní Ìlú Ìgàngàn.