Rose Odika
Nigerian Actress
Intro | Nigerian Actress | |
Places | Nigeria | |
is | Actor | |
Work field | Film, TV, Stage & Radio | |
Gender |
| |
Birth | 1970, Ibadan, Oyo State, Nigeria | |
Age | 55 years |
Rose Odika jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1988. Ó ti tó ọgbọ̀n (30) tí ó ti ń ṣiṣẹ́ sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá. Òun ni Gómìnà ẹgbẹ́ tíátà tí wọ́n ń pè ní Theater Arts and Motion Pictures Practitioners Association of Nigeria (TAMPAN) tí èka ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.