Phillip Adedotun Ogundeji
Nigerian Yoruba lecturer in English and theater
Phillip Adedotun Ogundeji je oluko omo ile Naijiria.
Oluko litireso Yoruba ni Phillip Adedotun Ogundeji ni eka-eko Eda-ede at Ede Aafirika ni UI Ibadan, Nigeria. Ori ere ori itage ni pupo ninu awon ise re da le lori. O ti gba oye ojogbon ni Yunifasiti yii.