Lola Alao
Nigerian actress
Intro | Nigerian actress | |
Places | Nigeria | |
is | Actor | |
Work field | Film, TV, Stage & Radio | |
Gender |
| |
Birth | 1 December 1969 | |
Age | 55 years | |
Star sign | Sagittarius |
Lola Rhodiat Alao (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1970) jẹ́ òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ Ìgbìrà ní ìpínlẹ̀ Kogí lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gẹ́gẹ́ bí òṣèré, ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì tí ó ju ọgọ́rùn-ún lọ.
Ní ìgbà èwe rẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà ni Army Children School, Ìlọrin. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Sóbí Government School. Ó kàwé gboyè dìgírì àkọ́kọ́ ní ifáfitì ìjọba àpapọ̀ to wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, (University of Lagos). Lọlá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà pẹ̀lú ère àṣàfihàn lórí tẹlifíṣọ̀nnù tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Ripples". Lẹ́yìn èyí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò ló ti kópa. Òun fún ara rẹ̀ tí ṣẹ olóòtú sinimá tó ju ọgbọ̀n lọ.