Adeoye Adewale
Nigerian Actor
Intro | Nigerian Actor | |
A.K.A. | Elesho | |
A.K.A. | Elesho | |
Places | Nigeria | |
is | Actor | |
Work field | Film, TV, Stage & Radio | |
Gender |
| |
Birth | 10 January 1959, Ikirun, Nigeria | |
Age | 66 years | |
Star sign | Capricorn |
Adéwálé Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ tí orúkọ àbísọ rẹ̀ gangan jẹ́ Adéwálé Adéoyè tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 1959 jẹ́ gbajúmọ̀ aláwàdà àti ọ̀ṣẹ̀rè sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá ọmọ bíbí ìlú Ìkirun ní ní ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́lódùn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni eré sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa. Ó ti tó ọdún mẹ́rìndínlógójì (36) tí Adéwálé Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá-àgbéléwò.
Bí Adéwálé Ẹlẹ́ṣọ̀ọ́ ṣe jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀ṣẹ̀rè, bẹ́ẹ̀ náà ló ń ṣe òṣèlú.