Adeniyi Johnson
Nigerian actor
Intro | Nigerian actor | ||||
Places | Nigeria | ||||
is | Actor | ||||
Work field | Film, TV, Stage & Radio | ||||
Gender |
| ||||
Birth | 27 February 1978, Lagos, Lagos State, Nigeria | ||||
Age | 46 years | ||||
Star sign | Pisces | ||||
Family |
| ||||
Education |
| ||||
Notable Works |
|
Adeniyi Johnson tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kejì ọdún 1978 (27th February 1978) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti ju ogún ọdún lọ tí ó ti ń ṣeré tíátà, ṣùgbọ́n ìràwọ̀ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní tàn nígbà tí ó kópa nínú eré orí tẹlifíṣàn kan tí àkọ́lé "Tinsel". Gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, Tóyìn Àìmàkhù ni ìyàwó àkọ́fẹ̀ Adéníyì Johnson, ṣùgbọ́n kò pẹ́ tí ìgbéyàwó wọn foríṣánpọ́n.